The Horse, The Man & The Son
Chief Commander Ebenezer Obey
19:34Èdùmàrè ló ń pèsè àti jẹ ìgbín (Èdùmàrè ló ń pèsè àti jẹ) Ìgbín ó lọwọ, arọ ko l'ẹsẹ o (Èdùmàrè ló ń pèsè àti jẹ) Bí o sì tèmi (ọrẹ òní lè jẹ) Bí o sì tèmi (ọrẹ òní lè mú) Ẹjọwọ ẹma sọ bẹẹ mó (Ọba Olúwa l'àlewi, lèse) Ẹjọwọ ẹma sọ bẹẹ mó (Ọba Olúwa l'àlewi, lèse) Rasaki Bàbá Iyabode tiwa Ọkọ Musili, awo jọji, ọkọ Abiola mi ọkan Wọn ní ìwọ o lówó, wọn ní ìwọ o kọlé Rasaki, wọn ní ìwọ o lówó (wọn ní ìwọ o kọlé) Olúwa lo ju ẹdá lọ, wón ó mò pé oyatọ Toba lówó lọwọ ko sọra Ọba Olúwa tó dá Mama Elewedu, lo dá Mama Alaso (Toba lówó lọwọ ko sọra, toba lówó lọwọ ko sọra) (Ọba Olúwa tó dá Mama Elewe, lo dá Mama Alaso) Táá ba lè ní bàa bá báni Ìwọn làá bàa ni ṣe ọtá mo, bóbàyà Bóbàyà, bóbàyà, ma fi ẹmí mí silẹ kin ma lọ