Olowo Laiye Mo

Olowo Laiye Mo

Chief Commander Ebenezer Obey

Длительность: 3:03
Год: 2010
Скачать MP3

Текст песни

Olowo laiye mo
Oluwa temi di owo re
Gbogbo lala eda
Nitori owo ni
Je ki aye mi dun
Se mi ki nle j' eniyan
Tete fi ona han mi
Maje kin lo lofo

Oluwa, ko si ore to da bi ire
Tete fi ona han mi Oluwa
Maje kin lo lofo
Je ki aye mi dun
Se mi kinle di eniyan
Tete fi ona han mi Oluwa
Maje kin lo lofo

Aye ki n se leni, ati po ni moje
Mako isura mi da, si tele awo san mo
Baba je pe mi, lati enu ona
Ko si tun le mi de, de ninu kaye mo

Oluwa, ko si ore to da bi ire
Tete fi ona han mi
Maje kin lo lofo
Je ki aye mi dun
Se mi kinle di eniyan
Tete fi ona han mi Oluwa
Maje kin lo lofo