Akira
Labisi
4:15Baba te'wọ gbà wá o Baba te'wọ gbà wá la Baba te'wọ gbà wá o Baba te'wọ gbà wá la (Easy concept) Bàbá gbà mí, bàbá gbà mí la K'ìjọba re, k'ìjọba tó dé o Bàbá gbà mí, bàbá gbà mí la (Jesu o) K'ìjọba re, k'ìjọba tó dé o Èmi kò ní ṣ'aláìní oun tó dára Nínú re ni èmi ṣa gbẹ́kẹ̀ mi lé Bàbá gbà mí, májẹ kin lo l'ofo Bàbá gbà mí, májẹ kin lo l'ofo Ah, Olódùmarè, baba te'wọ gbà wá ká má ṣíṣe l'ayé Ah, Olódùmarè, baba te'wọ gbà wá ká má ṣ'írin l'ayé o Ah, Olódùmarè, baba te'wọ gbà wá ká má ṣíṣe l'ayé Ah, Olódùmarè, baba te'wọ gbà wá o, ká má ṣíṣe l'ayé We call you Yahweh (Baba te'wọ gbà wa o) We call you Yahweh (Baba te'wọ gbà wá la) We call you Yahweh (Baba te'wọ gbà wá o) We call you Yahweh (Baba te'wọ gbà wá la) Ah, Olódùmarè, baba te'wọ gbà wá ká má ṣíṣe l'ayé Ah, Olódùmarè, baba te'wọ gbà wá o, ká má ṣíṣe l'ayé o Ah, Olódùmarè, bàbá te'wọ gbà wá ká má ṣíṣe l'ayé o Bàbá gbà mí, májẹ k'èmi lo l'ofo Bàbá gbà mí o, májẹ k'èmi lo l'ofo