Amona Tete Mabo
Pastor J. A. Adelakun
13:01Baba wa mbo o, Jesu mbo, ko nipe de mo Alagbara mbo, Jesu wa mbo wa Jesu wa mbo lati wa se dajo aye. Jesu mbo, ko nipe de mo Jesu mbo, ko nipe de mo Gbogbo oju ni yi o ri, at'awon to kan Jesu mo gi (oun mbo o) Jesu mbo, ko nipe de mo Alagbara mbo, Jesu wa mbo wa Jesu wa mbo lati wa se dajo aye Ti Jesu ba de Satani yi o fere ge Ti Jesu ba de Satani yi o d'awati o Satani kanjogbon, o kanjogbon o daran T'ori Jesu wa mbo lati wa se dajo aye Satani kanjogbon, kanjogbon o keran Satani kanjogbon, kanjogbon o daran T'ori Jesu wa mbo lati wa se dajo aye Ojo ti pe o, to ti n dale aye ru Ojo ti pe o, to ti n bale aye je Ka f'omo olomo seso Ise owo re ni (bee ni) Ka d'eniyan n'igbekun Ise owo re ni Eni to fe se ife Jesu Iwo lo de won lona o O daju, satani a jiya Ti Jesu ba de Satani kanjogbon, o kanjogbon mo loru gi oyin Tori Jesu wa mbo lati wa se dajo aye Satani kanjogbon, kanjogbon o keran Satani kanjogbon, kanjogbon o daran Tori Jesu wa mbo lati wa se dajo aye Gbogbo ayanfe o, e mura sile o Eyin ayanfe o, e mura de Baba o Eyin ayanfe, e jo e mura sile o Gbogbo ayanfe o, e mura de Baba Laipe ojo ta o mo o, Baba wa yi o yo, lawosanmo o Bi o ti yo pelu awon ogun orun T'on ko mimo mimo Eyin ayanfe, tori na e mura sile o Satani kanjogbon, kanjogbon ti Jesu ba de Satani a jiya o, ti Jesu ba de Tori Jesu wa mbo lati wa se dajo aye (o kanjogbon o) Satani kanjogbon, kanjogbon o keran Satani kanjogbon, kanjogbon o daran Jesu wa mbo lati wa se dajo aye (O fere de o) Satani kanjogbon, kanjogbon o keran Satani kanjogbon, kanjogbon o daran Jesu wa mbo lati wa se dajo aye Satani kanjogbon, kanjogbon keran Satani kanjogbon, kanjogbon o daran Jesu wa mbo lati wa se dajo aye. (end)