Mo Wa Dupe
Paul I.K. Dairo
5:49The remix, believe it or not (the remix, love) The remix, believe it or not (yeah), believe it or not, believe it or not (yeah) This is how it should be done (uh, uh) 'Cause this style is identical tonight (what, what?) How can I make you dance? (C'mon) PD, that's what you came here for, right? (That's what you came here for) (alright, alright) Ẹlẹda mi, mọ di ẹ mú Mọ di ẹ mú Ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, mi ò gbọdọ jabọ Ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, Baba, mo di ẹ mú Ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, mi ò gbọdọ jabọ Mo wà dùpẹ ore àná, Baba, mo dùpẹ o Mo wà dùpẹ ore eni, Baba, mo dùpẹ o Mo tún dùpẹ ore ọlá, Baba, mo dùpẹ o Baba, mo dùpẹ o, Baba, mo dùpẹ o Baba, mo dùpẹ o, Baba, mo dùpẹ Bí mo bá ji l'òwúrọ kùtùkùtù, ma d'orí mí mú Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o Bí mo bá ji l'òwúrọ kùtùkùtù, ma d'orí mí mú Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o (Baba) Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o (Baba) Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o Ọlọ́run àgbáyé, Ọlọ́run àgbáyé Ọlọ́run àgbáyé, Ọlọ́run àgbáyé Iwọ nìkan ni ìgbẹ́kẹ̀lé mí, ìwọ nìkan ni ìgbẹ́kẹ̀lé mí Baba, Baba, Baba, Baba, Baba, Baba, Baba, Baba, Olúwa B'ọmọdé ba dùpẹ ore àná, ari omiran gbá Kò ṣeni tó lè ṣe bí kí n ṣe iwọ o Bí mo bá ji l'òwúrọ kùtùkùtù, ma d'orí mí mú Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o Bí mo bá ji l'òwúrọ kùtùkùtù, ma d'orí mí mú, ah Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o (Baba) Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o (Baba) Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o Hm, o ya, hm, o ya, hm Ẹ jẹ ka dùpẹ lọwọ Ọlọrun, ei Ẹ jẹ ka dùpẹ lọwọ Ọlọrun, mo tí ṣorí rè Ẹ jẹ ka dùpẹ lọwọ Ọlọrun, ei-ei-ei Ẹ jẹ ka dùpẹ lọwọ Ọlọrun Ah, easy, woske, ah-ah, easy, oyo, ode-skeskeske Ẹlẹda mi, mo di ẹ mú Mo di ẹ mú Ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, Baba, mi ò gbọdọ jabọ Ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, mọ di ẹ mú Ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, mi ò gbọdọ jabọ Ọlọ́run àgbáyé, Ọlọ́run àgbáyé Ọlọ́run àgbáyé, mi ò gbọdọ jabọ Kò ṣeni tó lè ṣe bí kí n ṣe iwọ o, kò ṣeni tó lè ṣe bí kí n ṣe iwọ o Atẹrẹrẹ kárí ayé Bí mo bá ji l'òwúrọ kùtùkùtù, ma d'orí mí mú, ah Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o Bí mo bá ji l'òwúrọ kùtùkùtù, ma d'orí mí mú Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o Baba, mo dùpẹ o, Baba, mo dùpẹ o (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) Baba, mo dùpẹ o, Baba, mo dùpẹ (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) Mo tí ṣorí rè, Baba, mo tí ṣori rè, Baba o (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) Mo tí ṣorí rè, Baba, mo tí ṣori rè, Baba o (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) Atẹrẹrẹ kárí ayé (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) Atẹrẹrẹ kárí ayé o (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) (Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) bí mo bá ji l'òwúrọ kùtùkùtù... Baba, Baba (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) Baba, o ṣe, Baba, o ṣe (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) Mo dùpẹ o, mo dùpẹ o (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) Mo dùpẹ lọwọ rẹ, Baba (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) Mo dùpẹ, mo dùpẹ, mo dùpẹ (mo ṣorí rè o, Ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) (Mo ṣorí rè o, Ẹlẹda...)