Apata Aiyeraiye

Apata Aiyeraiye

The Choir Of Cherubim And Seraphim Movement Church, Surulere

Альбом: Oke Mimo
Длительность: 5:31
Год: 2016
Скачать MP3

Текст песни

Apata Aiyeraye se ibi isa di mi
Je ki omi oun eje
To san lati iha re
To sa lati iha re
Se iwosan fe se mi
Apata Aiyeraye se ibi isa di mi
je ki omi oun eje
To san lati iha re
To sa lati iha re
Se iwosan fe se mi

Ko sohun ti mo muwa
Mo romo agbelebu
Igi oro, igi iya
Ta kan olugbala mo
Laikun, lai sawawi
Bi aguntan ni waju olu rerun
Oyadi ko ti le fohun
Oku fun te mi ti re

Apata Aiyeraye se ibi isa di mi
Je ki omi oun eje
To san lati iha re
To sa lati iha re
Se iwosan fe se mi

Iku oro lori igi, oko egbe, oti kikan
Wonyi niya ti olugbala je
Nitori temi tire
Iwo yo tun kan mo gi bi?
Pelu ise ati iwa owo re
Ronu piwada, ko ese sile
Ka ri o sinu ife baba

Apata Aiyeraye se ibi isa di mi
Je ki omi oun eje
To san lati iha re
To sa lati iha re
Se iwosan fe se mi

Gbe agbelebu re
Bo wu wo bi ko wu wo
Ma to jesu lehin
Ko bo ninu ebi
Gbe agbelebu re
Bo wu wo bi ko wu wo
Ma to jesu lehin
Ko bo ninu ebi

Abi owo loun wa
Ore mi figbagbo gbe
Gbe agbelebu re
Bo wu wo bi ko wu wo
Ma to jesu lehin
Ko bo ninu ebi

Omo loun wa
Eyi lo n dun o lokan
Gbe agbelebu re
Bo wu wo bi ko wu wo
Ma to jesu lehin
Ko bo ninu ebi

Owase wa se, o ri se
So nigbagbo
Gbe agbelebu re
Bo wu wo bi ko wu wo
Ma to jesu lehin
Ko bo ninu ebi

O nile lori, Abonile yo e lenu
Gbe agbelebu re
Bo wu wo bi ko wu wo
Ma to jesu lehin
Ko bo ninu ebi

Ki loun to n dun o lokan
To le bore so
Gbe agbelebu re
Bo wu wo bi ko wu wo
Ma to jesu lehin
Ko bo ninu ebi

Bere gbe, Bere gbe, Bere gbe, Bere gbe
Afuye
Gbe agbelebu re
Bo wu wo bi ko wu wo
Ma to jesu lehin
Ko bo ninu ebi

Fayo gbe, Fayo gbe, Fayo gbe, Fayo gbe
Afuye
Gbe agbelebu re
Bo wu wo bi ko wu wo
Gbe agbelebu re
Bo wu wo bi ko wu wo
Ma to jesu lehin
Ko bo ninu ebi
Ma to jesu lehin
Ko bo ninu ebi