Genesis (Feat. Flavour)
Zlatan
3:08Hustle everyday and night Pray make them no stain my white Even when I go all the way (still many people go backbite) The future bright Every likkle thing would be alright You can never know who is who (pray make oluwa dey my side) Mo pe alpha ati omega Afi ko dide ja Afi ko ṣaanu mi Afi ko ja fun mi Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni Ko yẹ ko maa lọ bee Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ Iya ati baba lọla lo bi mi ṣugbọn mo tunra mi bi Ẹlẹdaa mi fẹ sun mo dabara bo o ko ji Darukọ iṣẹ jamajama kan ti mi o ṣe ri Mo gbe pọnnpọ pa sẹ diẹ lo ku sẹ ki igun mi pa lori Baba pastor o tete mọ pe zanku n fo window lo si show, dagboru pẹlu kito Femi brookeey lo kọkọ mu mi lọ si studio Orin were mo kọ ju, awọn temi lo dun bi kopiko Mi o le gbagbe awọn niggaa mi, awọn l'ọn ginger mi Ti n ba wa owo studio ti wọn a towo bapo knicker mi Ten toes on my grind nisin mo dọmọ to sabi Up agbede ni ikorodu awọn temi l'onigari That time Oh my lordy wọn ni ko le lọ far Wọn ni bawo lẹni ti o niṣẹ ṣe ma san tithes (awọn bastard) Bi orukọ ọmọ mi toluwalaṣẹ Unstoppable bo wun wọn k'ọn gbajẹ Mo pe alpha ati omega Afi ko dide ja Afi ko ṣaanu mi Afi ko ja fun mi Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni Ko yẹ ko maa lọ bee Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ Mo pada dọmọ t'ọn fi n yangan Ọmọ t'ọn fi n tọrọ, irọ o da ma mẹnu le ọmọ jọmọ lọ Pain in the ass ti o common fun awọn doubting Thomas Eewo ti mu wọn lẹnu aje wọn le sọrọ mọ I go dey always remember When I wan cook but gas no dey cylinder I was born to do wonders But ogun idile no wan gimme chance Never you say never My life story na big ginger 'Symbol of hope', e dey play, e dey choke Steady motivation fawọn temi ninu hole Mo pe alpha ati omega Afi ko dide ja Afi ko ṣaanu mi Afi ko ja fun mi Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni Ko yẹ ko maa lọ bee Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ Ko yẹ ko maa lọ bee Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ