Jies

Jies

Bnxn

Альбом: Captain
Длительность: 2:53
Год: 2025
Скачать MP3

Текст песни

Titi, Jola ati Folukemi

Ọlọ́run, baby your boyfriend kó lè kpa opor
I'm chilling and I'm listening to Westlife, Soledad, ṣ'o mo?
Fine girl the thing you carry for brasier, kó gbé wa, opor
Hmm, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn (ju ìdí ẹ sẹ́yìn)

Shola (gbé wa), the kind shima (shima)
Ton ma n gbewa, aromashina
So I dey tell Shola, ton ba n koja, ko má you lo, ko ṣa ma gbé wa
You give me, give me, shey make we pause for here? Or make we continue
Abere gbọ́dọ̀ sọnù, a ma wa jade f'ohùn, a ma wa jáde f'ohùn
I saw geronimo
Before I fight for you
Deep feeling oh, way too nice

Ọlọ́run, baby your boyfriend kó lè kpa, opor
I'm chilling and I'm listening to Westlife, Soledad, ṣ'o mo?
Fine girl the thing you carry for brasier, kó gbé wa, opor
Hmm, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn (ju ìdí ẹ sẹ́yìn)

Orobo ti o gb'owo lépa, and we go still see whenever
When I dey pour champagne-lele
Chelsea for back, like Makelele ok lele
Mama church mo fẹ́ ko wa, money full my short nikka
Twenty bottles of champaign-lele
And for my guys and young ladies say again, again
Again, again, again, and now you're all over my brain
And I cannot concentrate on
Wetin I come here do again? I'm now contented
Let's get back to defenseless

Ọlọ́run, baby your boyfriend kó lè kpa opor
I'm chilling and I'm listening to WestLife, Soledad, ṣ'o mo?
Fine girl the thing you carry for brasier, kó gbé wa, opor
Hmm, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn (ju ìdí ẹ sẹ́yìn)
Ọlọ́run, baby your boyfriend kó lè kpa opor
I'm chilling and I'm listening to WestLife, Soledad, ṣ'o mo?
Fine girl the thing you carry for brasier, kó gbé wa, opor
Hmm, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn, ju ìdí ẹ sẹ́yìn (ju ìdí ẹ sẹ́yìn)

Shola àti Folukemi (yo ìdí e sẹ́yìn)
Ṣ'ori Fola gbàgbé àwọn ọrẹ mi (yo ìdí e sẹ́yìn)
I want make you out am for my body (yo ìdí e sẹ́yìn)
Ma fún e gbogbo owo mi to ba (yo ìdí e sẹ́yìn)